KIKO YORUBA NI AKOYE 2
$19.01
$37.07
Kiko Yoruba Akoye ni ilana eto eko kari-aye. Ede yoruba je okan pataki ninu awon ede abinibi ni agbaye. Ede yoruba, asa yoruba ati ihuwasi awon omo ile yoruba ti di ohun ti won n ko ni orisirisi ile-eko giga kaakiri agbaye. America ni o, ile Geesi ni o, Russia ni o ati bee bee lo. Eni ti yoo si fun ni ni aso wo, ti orun re la koko wo naa. Akowe:Qiògbón Adédejl Awóníyì, Alàgbà Lásún Adéwolé, Alàgbà Lásúnkànmi Tệllà. Categories: Primary, primary book, Yoruba Tags: Akoye, KIKO YORUBA, KIKO YORUBA NI AKOYE 2, yoruba
Primary